Post
Topic
Board Other languages/locations
Re: Yoruba language
by
abdulfatah.busari
on 01/06/2020, 14:54:36 UTC
Waawu! O ya mi l'enu l'opo l'opo lati ri wipe ede Yoruba ni aaye oto l'ori website yi. Inu mi si dun sii gidi gidi ni. Nje a ri eni ti o le fun mi ni merit? Inu mi yio dun gidi gaan ni. Ese pupo pupo...
Kilo je "Waawu" nibiye? Shey nyi je ijile ede Yoruba ni? Mo ro kpe ede English niye.

Modúpé gidigidi fún meriti tí e fi dá mi Lola o.
Mon lóore o