Waawu! O ya mi l'enu l'opo l'opo lati ri wipe ede Yoruba ni aaye oto l'ori website yi. Inu mi si dun sii gidi gidi ni. Nje a ri eni ti o le fun mi ni merit? Inu mi yio dun gidi gaan ni. Ese pupo pupo...
Kilo je "Waawu" nibiye? Shey nyi je ijile ede Yoruba ni? Mo ro kpe ede English niye.

Otito ni oro ti e so...ede ayalo ni a le kaasi. Sugbon ju gbogbo re lo, mo dupe gidigidi l'owo yin fun bi e ti se fun mi ni merit ti mo beere fun. ko ni tan lowo yin o! Amin! Eseun leekan si