Gege bi ofin forumu yi lati ni ede Naijiria kan Lati soro ti Yoruba je okan larawon. Velas network se ikede ajosepo re pelu space chain ni ojo meta seyin,ile ise mejeji yi yangan nipa ifowosowopo won,nitori wipe wonje okan lara awon blockchain akoko tinsise ni agbaye.
Ifowosowopo awon ile ise mejeji yi(velas ati space chain) je ipinnun fun aseyori gidi nitoriwipe space chain yoo ni anfani ninu okan ninu awon imo ero block chain tio yara julo, Alelo velas EVM token ninu Ethereum netiwoki Lati yi VLX pada si Ethereum, space chain je ajo ti oda space ati block chain po Lati ko sisikale blockchain to da Lori satellite.