Mo ki gbogbo ile oooooo omoluabi a gbe wa ooooooooo oruko temi ni Nathrixxx ni forum apejopo was yi, inu mi dun pupo lati was laarin awon omo iya mi tooto, omo ilu Oyo ni ogbomoso ajilete ni bi ti nwan tin mu eko yangan Lori Amala to gbona felifeli, oruko ile baami ni ile abgoro ni eyin okeleerin adugbo aaje.
I'm not Yoruba but two of the most important words which I heard most frequently during my brief stay in Kwara State, Oyo State and Ogun State and even among Yorubas in non-yoruba speaking states are:
1- eloni (how much?)
2- Soro Soke (speak up) - This one has an emotional undertone for me. We know why already.
Posted on: September 08, 2021, 05:18:35 PMPosted by: Nathrixxx
Insert Quote
Mo ki gbogbo ile oooooo omoluabi a gbe wa ooooooooo oruko temi ni Nathrixxx ni forum apejopo was yi, inu mi dun pupo lati was laarin awon omo iya mi tooto, omo ilu Oyo ni ogbomoso ajilete ni _act_ bi ti nwan tin mu eko yangan Lori Amala to gbona felifeli, oruko ile baami ni ile abgoro ni eyin okeleerin adugbo aaje.
Posted on: September 07, 2021, 07:15:25 PMPosted by: adeyemirichard71
Insert Quote
Ekale ooooh Eyin temi bawo ni, inumidun