Eyin temi bawo ni, adeku Orilede wa yin olorun ama bá denku orisirisi to selé ninu dié toku kì odun Eyin pari edumare awa pelu wa tebi tara.
Posted on: September 22, 2021, 02:00:44 AMPosted by: Mpamaegbu
Insert Quote
Quote from: Davidvictorson on September 17, 2021, 04:00:06 PM
I'm not Yoruba but two of the most important words which I heard most frequently during my brief stay in Kwara State, Oyo State and Ogun State and even among Yorubas in non-yoruba speaking states are:
1- eloni (how much?)
2- Soro Soke (speak up) - This one has an emotional undertone for me. We know why already.
And you didn't hear all the "Eku igbadu"? and "Eku Alejo"? That means you didn't flex while you were there then 😅
Posted on: September 17, 2021, 04:00:06 PMPosted by: Davidvictorson
Insert Quote
Quote from: Nathrixxx on September 08, 2021, 05:18:35 PM
Mo ki gbogbo ile oooooo omoluabi a gbe wa ooooooooo oruko temi ni Nathrixxx ni forum apejopo was yi, inu mi dun pupo lati was laarin awon omo iya mi tooto, omo ilu Oyo ni ogbomoso ajilete ni bi ti nwan tin mu eko yangan Lori Amala to gbona felifeli, oruko ile baami ni ile abgoro ni eyin okeleerin adugbo aaje.
I'm not Yoruba but two of the most important words which I heard most frequently during my brief stay in Kwara State, Oyo State and Ogun State and even among Yorubas in non-yoruba speaking states are:
1- eloni (how much?)
2- Soro Soke (speak up) - This one has an emotional undertone for me. We know why already.
Posted on: September 08, 2021, 05:18:35 PMPosted by: Nathrixxx
Insert Quote
Mo ki gbogbo ile oooooo omoluabi a gbe wa ooooooooo oruko temi ni Nathrixxx ni forum apejopo was yi, inu mi dun pupo lati was laarin awon omo iya mi tooto, omo ilu Oyo ni ogbomoso ajilete ni bi ti nwan tin mu eko yangan Lori Amala to gbona felifeli, oruko ile baami ni ile abgoro ni eyin okeleerin adugbo aaje.
Posted on: September 07, 2021, 07:15:25 PMPosted by: adeyemirichard71
Insert Quote
Ekale ooooh Eyin temi bawo ni, inumidun pe MO wa nibi.
Ede yoruba ATI Asa yoruba MA gbe wa ooo
Ayewada koni baje fun wa
Posted on: August 08, 2021, 06:02:15 PMPosted by: Issa56
Insert Quote
Oye ka le ma reran wa lowo pelu merit nibi. Lati ma ran our omo yoruba lowo lati ma sha awon ishe signature.
Posted on: May 10, 2021, 07:04:43 AMPosted by: Charles-Tim
Insert Quote
Quote from: laycon on September 26, 2020, 04:00:16 PM
Inu mi dun lopo lopo wipe anfani wa fun wa lati so ede abi nibi wa ton se Yoruba. Aba kon soso ti moni ni wipe awon ara wa ti won ba ti wa loke ninu forumu Yi ni lati ran awa ti aba sese bere(newbie) lati de oke ninu forumu Yi. Aba mi o ju yelo
Otito ni wipe ede Yoruba o dara lopo lopo, sugbo a ni opo lopo lati se lati te si iwaji. A ni lati mo nipa bitcoin ati altcoin, ki awa lara awon ti o ma posti ni board gbogbogbo, nipa eyi, a ma te siwaju. O ma dara ki a wa si ibi lati ni ajoro ati lat _act_ i beere ohun ti a ba mo nipa bi a se le lo bitcoin ati altcoin.
Posted on: September 26, 2020, 04:00:16 PMPosted by: laycon
Insert Quote
Inu mi dun lopo lopo wipe anfani